![]()
|
FOR MORE INFORMATION ABOUT IFA AND ORISA PLEASE CONTACT THIS ADDRESS |
EIYE WEWE ABIYE PELEPELE EIYE NLA ABIYE NLANLA AIGBO N LA TI MAA FO RAGAGI RAGAGI LEGAN AWON NI WON DA IFA FUN AWON ELEYE NIGBATI WON GBE ERU NI ILE OLODUMARE WON DE ILE ALARA.WON SO KALE,WON KO RI BI GBE ERU SI. WON TUN DE ILE AJERO,WON KORI BI GBE ERU WON SI WON TUN DE ILE ORANGUN AGA,WON KO TUN RIBI GBE ERU WON SI. WON DE ODE AIYE,AKOKO NIKI E SO KALE WA. ONI ESETI EFI DE ILU TI EKO BEERE LOWO ONILU,WON NI NLE OSE AKOKO OLUMORAN AYE, NIBE NI WON SOKALE SI, WON LO KO ILE ALARA,WON KOWA FUN AKOKO, WON LO KO ILE AJERO,WON KO WA FUN AKOKO, BAKANNA WON TUN LO KO TI ORANGUN AGA,WON KO FUN AKOKO OLUMONRAN AIYE, NJE MO PEYIN BAYI,KI E LO KO ILE OLORO ATI OLOLA WA FUN MI. ASE O,ASE NITI IFA,ASE NI TI EDUMARE,TOO NITI OLUWO. IGBO RERE NOMO DE, MORI EKE RERE SE, ODAN IRE NI MO WO, MORI OKUN IRE FA, NIGBATI MODE ODE AGBELE, MORI ALAWO IRE GBELE MI, AWON ENI META YII NI WON DA IFA FUN ORUNMILA NIGBATI BABA NLO SILEKUN OLA TI WON TI LOTUIFE, TI ONLO FI ESE MEEJEJI BE SINU IGBA AJE SA SU, ONI IDE MI O,E PE KI E TO TENI DE. OWENREN OWENREN,IDE NI KI E DE LONI DANDAN,.APAMOWO NI EFUN OLELE NPAJE TIRE,GBO GBO ARA NI SEFUNSEFUN FISE AJE,ASE ASE ASE NITI EDUMARE. |
|
|
|
Title
|
Author
|
|
FALOLA ADESANYA Egbe Ifa Ode Remo phone no: +2348060160465
|
|
|
FALOLA ADESANYA Egbe Ifa Ode Remo phone no: +2348060160465
|
|
|
FALOLA ADESANYA Egbe Ifa Ode Remo phone no: +2348060160465
|
|
|
AWO FAFEMI FATALABI Egbe Awo Tosin Ukraine |
|